TWOGBS Audio

by Moses Jesutoki

free


not available



"TWOGBSAudio.apk" is an intuitively designed App to download the Audio files required for the “BMO_KJV+Yor Kika” and “KJV_BMO+KJV Audio” Applications by the Word of God Bible Society. These two Bible applications are written to study the Bible easily.Install "TWOGBSAudio.apk" from “Google Play Store” to download the Bible book or books you want these Bible Apps to play; with little donation for the procurement and maintenance of Bible press. You only need to download the Bíbélì Mímó̩ onítumò̩ audio for “BMO_KJV+Yor Kika”; and the KJV Audio for “KJV_BMO+KJV Apps respectively. But, you need to download both if you installed both Bible Applications, and you want each of the Bible App to read any Book for you either in Yoruba and/or English respectively.The App can play the Audio without the need for internet after downloading the Bible Book Audio."TWOGBSAudio.apk" jé̩ ètò tí ó ro̩rùn fún mùtúmùwà láti lò fún gbígba òǹkà Bíbélì tí ó po̩-dandan fún kíka Bíbélì pè̩lú ètò ìka Bíbélì tí àwo̩n e̩gbé̩ "the Word of God Bible Society" s̩e láti kó̩ Bíbélì pè̩lú ìrò̩rùn. Gba ètò "TWOGBSAudio.apk" láti “Google Play Store” láti s̩e è̩dà ìwé Bíbélì tí o fé̩ kí ètò kíka Bíbélì tí o ti gbà sórí è̩rò̩ re̩; pè̩lú è̩bùn owó ráńpé̩ fún ríra, àti láti s̩e ìtó̩jú è̩ro̩ títe̩ Bíbélì. O nílò láti s̩e è̩dà òǹkà ìwé Bíbélì tí ó wà lé̩hìn tí o bá ti fí ìka tó̩ bó̩tínnì “Bíbélì Mímó̩ onítumò̩” kí ó lè ka Bíbélì Yorùbá fún o̩ pè̩lú ètò “BMO_KJV+Yor Kika”; o sì nílò ti èyìí tí ó wà nígbà tí o bá fí ìka tó̩ bó̩tínnì "KJV Audio" fún kíka Bíbélì Òyìnbó fún o̩ pè̩lú ètò “KJV_BMO+KJV". S̩ùgbó̩n tí o bá ti gba ètò méjèèjì sílè̩, tí o sì fé̩ kí wó̩n ka Bíbélì Yorùbá àti ti èdè Òyìnbó fún o̩, gbogbo òǹkà náà ni o gbo̩dò̩ s̩e è̩dà wo̩n sínú e̩ro̩ re̩. O kò nílò è̩ro̩ ayélujára mó̩ fún gbígbó̩ ìwé Bíbélì ti o ti gba òǹkà rè̩ sílè̩.